Editor's PickFeaturedIn PictureNatureNewsOthersPolitics

Ni Ilu Ọ̀yọ́, Taani Afobaje? Oyomesi Abi Ifá?

Old photo of the Alaafin of Oyo
Old photo of the Alaafin of Oyo

A kìí fí Ifá yàn Ọba l’Oyo. Ó pé kí Ọ̀yọ́ too mọ nípa Ifa.
E ètò àti ìlànà tí Ọ̀yọ́ ni pé bí Ó bá bá wà ja, Aremo lọ máa bosori ìtẹ́.
Bí kò bá sì Aremo, Oyomesi ni yóò mú ọmọ òye láàrín wọn Akeyo(ọmọ ọba) tó bá wù wón.

Bí Ayaba Aláàfin tó bá waja bá wà nínú oyún, tí Ọba kò sì ní ọmọkùnrin tó lè gorí ìtẹ́, Basorun àti Ayaba tó wà nínú oyún ni yoo maa ṣe ijoba títí Ayaba ó fi bí ọmọ inú rẹ̀.

L’aye Aláàfin Onigbogi (1497) ni wọ́n kọ́kọ́ mú Ifá wọ Ọ̀yọ́ láti Ìlú Ọ̀tá, ṣùgbọ́n àwọn Oyomesi kò gbà á gẹ́gẹ́bí ìlànà ìfinijoyè. Onigbogi yí ni Aláàfin keje.
Àkọsílẹ̀ adayeba tún fi yé wa pé ní ìgbà Aláàfin Òfinran, wọ́n tún mú Ifá wá láti Ado (Akọ mo dájú bóyá Ado Odò ni tàbí Ado Awaye). Sugbon ẹ̀rí wá títí di òní pé lehin ti Òyómèsì bá ti mú Aláàfin titun, Babaláwo láti Adó Àwáyè máa ń wá sí Òyó láti dá Ifá kí wọn ó lè mọ bí àkókò Ọba titun yóò ṣe rí, ati awon ètùtù tí yóò mú Òyó tòrò. Ifá dídá yí kò ní nkankan ṣe pelu yíyan Ọba

Lẹyin ti Ọranyan waja Ajaka lọ joba
Lẹyin Ajaka, Aremo rè Aganju joba
Lẹyin Aganju-Basorun Ẹranko gbiná ló ńṣe ijoba títí tí Ayaba Iyayun fi bí Korì
Lẹyin Kori Aremo rẹ Oluaso lọ joba
Lẹyin Oluaso Aremo rẹ Onigbogi joba
Lẹyin Onigbogi Aremo rẹ Òfinran lọ joba
Onigbogi kò bi’mo
Àbúrò rè Orompoto ọkùnrin lọ jọba.
Gbogbo àwọn tó tún jẹ́ láti orí Orompoto láti orí Baba sì Aremo ni:
Ajiboye de, Abipa, Obamoro, Agannaerin, Obalokun, Ajagbo

Aláàfin Kan rán náà je Aremo Odarawu. Aremo Kanran tí ó jé ọmọ Jayin lọ tún jọba ní 1665.

ALSO READ: Ogedengbe Agbógungbórò: The Itinerant Warrior

Nígbàtí Jayin waja, Aremo rẹ, Olùsọ tí kú lójú Baba rè
Omo_omo Jayin, tíì ṣe ọmọ Olusi (Ayibi) lọ je Aláàfin
Lehinti Ayibi waja Aremo rè Osinyango lọ je Aláàfin.

Aláàfin méjo tó jẹ́ kí Ifá Tóò wo Oyo akọ fi Ifá yàn wọn.
Aláàfin mokanla tó jẹ́ lẹ́hìn tí Ifá wo Oyo, a kò fi Ifá yàn wọ́n.

Aláàfin Ojigi to je lẹhin Osinyango, àwọn Oyomesi lọ yàn kìí se Ifá.
Oyomesi náà lọ sí yán Aláàfin mẹ́rìnlá tó jẹ́ lẹhin Osinyango.

Ṣe Ifá lọ yàn Atiba?
Nígbà tí ó kàn Aláàfin Atiba ni Oyo Atiba, nkan yàtò díè
Gbogbo wa là mo pe Atiba lọ yàn Oyomesi, tí ó sì fi Lajide (Iranse Onasokun) je Onasokun Baba Oba.
Lẹhin Adewinmbi Atiba Aremo rẹ Adelu lọ jọba. Kò lowo Ifá ninu
Lẹhin Adelu Adeyemi je Aláàfin, Oyomesi lọ fii je. Kii se Ifá.
Lẹhin Adelu, Adeyemi je Aláàfin gẹ́gẹ́ bí Oyomesi ṣe fe
Lẹhin náà, Aremo Adelu, Láwàní Agogoija je Aláàfin ni àgbà lagba.
Nítorí ìwà réré rè, at bí ìlú ṣe toro nígbà tí ó wà lórí òye, Oyomesi pinnu (kì í ṣe Ifá) láti fi ọmọ rẹ Siyanbola je Aláàfin di pò rè.
Ìwà ìkóni móra, àlejò sise, àti jíjẹ gbajúmò laarin ìlú àti àgbègbè ló mú kó Oyomesi fi Adeniran, Aremo Adelakun náà je Aláàfin lẹ́hìn tí Ladigbolu waja. Kii se Ifá bí kò ṣe ìhà tí ó kó sì àwọn ará ìlú àti Oyomesi
Aremo Ladigbolu wá nínú àwọn tó dù òye kí Oyomesi tó mú ẹniti o wu wọ́n
Oyomesi náà lọ sí fi Orimadegun jẹ́ Aláàfin lẹhin ti Adeniran waja.

Oyomesi ni Ilu. Àwọn sí ní Afobaje ni Ilu Ọ̀yọ́. Kii ṣé Ifá.
Wọn mbere itosona bí asiko Ijoba Aláàfin titun yóò ṣe rí lọ́wọ́ Ifá Leyin ti wọn ba ti yàn án tán ni Kii ṣé pé Ifá tàbí Babaláwo lo n yan Aláàfin.

Láti ọwọ KAMA Gbàgbé Ìbẹ̀rẹ̀

Ẹ sinmi agbaja!

One thought on “Ni Ilu Ọ̀yọ́, Taani Afobaje? Oyomesi Abi Ifá?

  • Fay Schey

    Dear fountainnewsbreakerng.com Owner.

    This is Fay and I ran across fountainnewsbreakerng.com a moment ago.

    Looks great… but now what?

    By that I mean, when someone like me finds your website – either through Browsing or just bouncing around – what happens next? Do you get numerous of leads from your site, or at least enough to make you satisfied?

    Truthfully, most business websites fall short when it comes to generating paying customers. Studies show that 70% of a site’s visitors vanish and are gone forever after just a moment.

    Here’s an idea…

    How about making it really EASY for every visitor who arrives to get a personal phone call from they hit your site…

    You can –

    Web Conversion is a software widget that’s works on your site, set to capture any visitor’s Name, Email address and Phone Number. It signals you the moment they tell you they’re interested – so that you can talk to that lead while they’re actually looking over your site.

    CLICK HERE https://bit.ly/3LPltcD to test a Live Demo with Lead Conversion now to see precisely how it works.

    You’ll be surprised – the difference between contacting someone within 5 minutes versus a half-hour or more later could increase your results 100-fold.

    It gets even better… once you’ve captured their phone number, with our new SMS Text With Lead feature, you can automatically start a text (SMS) conversation.

    That way, even if you don’t close a deal instantly, you can follow-up with text messages for new offers, content links, even just “how you doing?” notes to develop a relationship.

    Very sweet – AND effective.

    CLICK HERE https://bit.ly/3LPltcD to learn what Web Visitors Into Leads can do for your business.

    You could be converting up to 100X more leads today!

    Fay
    PS: Lead Conversion offers a FREE 14 days trial – and it even includes International Long Distance Calling.
    You have customers waiting with you right now… don’t keep them waiting.
    CLICK HERE https://bit.ly/3LPltcD to try Lead Conversion now.

    If you’d like to unsubscribe click here https://bit.ly/3rD0G5c

    Only a quick note – the identities and email employed in this note, Fay and Schey, are stand-ins and not really real contact information. We cherish honesty and wished to confirm you’re aware! Should you want to connect with the real one behind this message, do check out our website, and we’ll associate you with the proper individual.

    Reply

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *